Esek 36:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ẹmi mi sinu nyin, emi o si mu ki ẹ ma rìn ninu aṣẹ mi, ẹnyin o pa idajọ mi mọ, ẹ o si ma ṣe wọn.

Esek 36

Esek 36:25-34