Esek 33:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti emi o sọ ilẹ na di ahoro patapata, ọ̀ṣọ nla agbara rẹ̀ kì yio si mọ, awọn oke Israeli yio si di ahoro, ti ẹnikan kì yio le là a kọja.

Esek 33

Esek 33:18-33