Emi o si san ẹsan nla lara wọn nipa ibáwi gbigbona; nwọn o si mọ̀ pe, emi li Oluwa, nigbati emi o gbe ẹsan mi le wọn.