Esek 14:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) AWỌN kan ninu awọn àgba Israeli si wá sọdọ mi, nwọn si joko niwaju mi. Ọ̀rọ Oluwa si tọ̀ mi wá, wipe,