Esek 12:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti o yi i ka lati ràn a lọwọ, ati gbogbo ọwọ-ogun rẹ̀, ni emi o tuká si gbogbo afẹ̃fẹ, emi o si yọ idà le wọn.

Esek 12

Esek 12:6-18