Eks 40:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tàn fitila wọnni siwaju OLUWA; bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose.

Eks 40

Eks 40:24-34