Eks 40:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA si sọ fun Mose pe,

2. Li ọjọ́ kini oṣù kini ni ki iwọ ki o gbé ibugbé agọ́ na ró.

3. Iwọ o si fi apoti ẹrí nì sinu rẹ̀, iwọ o si ta aṣọ-ikele ni bò apoti na.

Eks 40