Eks 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati OLUWA ri pe, o yipada si apakan lati wò o, Ọlọrun kọ si i lati inu ãrin igbẹ́ na wá, o si wipe, Mose, Mose. On si dahun pe, Emi niyi.

Eks 3

Eks 3:1-14