Eks 29:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si mú igẹ̀ àgbo ìyasimimọ́ Aaroni, iwọ o si fì i li ẹbọ fifì niwaju OLUWA; ìpín tirẹ li eyinì.

Eks 29

Eks 29:20-29