Eks 23:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ki yio lé wọn jade kuro niwaju rẹ li ọdún kan; ki ilẹ na ki o má ba di ijù, ki ẹranko igbẹ́ ki o má ba rẹ̀ si ọ.

Eks 23

Eks 23:23-31