Eks 22:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi olohun ba wà nibẹ̀, on ki yio san ẹsan: bi o ba ṣe ohun ti a fi owo gbà lò ni, o dé fun owo igbàlo rẹ̀.

Eks 22

Eks 22:6-18