Ẹk. Jer 3:40-43 Yorùbá Bibeli (YCE)

40. Jẹ ki a wádi, ki a si dán ọ̀na wa wò, ki a si tun yipada si Oluwa.

41. Jẹ ki a gbe ọkàn ati ọwọ wa soke si Ọlọrun li ọrun.

42. Awa ti dẹṣẹ, a si ti ṣọtẹ: iwọ kò ti dariji.

43. Iwọ ti fi ibinu bora, o si ṣe inunibini si wa: iwọ ti pa, o kò si ti dasi.

Ẹk. Jer 3