Ẹk. Jer 3:33-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. Nitori on kì ifẹ ipọn-ni-loju lati ọkàn rẹ̀ wá, bẹ̃ni kì ibà ọmọ enia ninu jẹ.

34. Lati tẹ̀ gbogbo ara-tubu ilẹ-aiye mọlẹ li abẹ ẹsẹ rẹ̀.

35. Lati yi ẹ̀tọ enia sapakan niwaju Ọga-ogo julọ.

Ẹk. Jer 3