Deu 7:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iwọ ba wi li ọkàn rẹ pe, Awọn orilẹ-ède wọnyi pọ̀ jù mi lọ; bawo li emi o ṣe le lé wọn jade?

Deu 7

Deu 7:8-22