Deu 31:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o fi oju mi pamọ́ patapata li ọjọ́ na, nitori gbogbo ìwabuburu ti nwọn o ti hù, nitori nwọn yipada si oriṣa.

Deu 31

Deu 31:8-22