Deu 30:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò sí li ọrun, ti iwọ iba fi wipe, Tani yio gòke lọ si ọrun fun wa, ti yio si mú u wá fun wa, ki awa ki o le gbọ́ ọ, ki a si le ṣe e?

Deu 30

Deu 30:3-19