Deu 28:61 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo àrun pẹlu, ati gbogbo iyọnu, ti a kò kọ sinu iwé ofin yi, awọn ni OLUWA yio múwa bá ọ, titi iwọ o fi run.

Deu 28

Deu 28:53-65