Deu 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si pada, mo si sọkalẹ lati ori òke na wá, mo si fi walã wọnni sinu apoti ti mo ti ṣe; nwọn si wà nibẹ̀, bi OLUWA ti paṣẹ fun mi.

Deu 10

Deu 10:1-15