Deu 1:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua ọmọ Nuni, ti ima duro niwaju rẹ, on ni yio dé ibẹ̀: gbà a ni iyanju; nitoripe on ni yio mu Israeli ní i.

Deu 1

Deu 1:36-46