Dan 7:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iwo mẹwa, lati inu ijọba na wá ni ọba mẹwa yio dide: omiran kan yio si dide lẹhin wọn, on o si yàtọ si gbogbo awọn ti iṣaju, on o si bori ọba mẹta.

Dan 7

Dan 7:18-28