Amo 3:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

A le fun ipè ni ilu, ki awọn enia má bẹ̀ru? tulasi ha le wà ni ilu, ki o má ṣepe Oluwa li o ṣe e?

Amo 3

Amo 3:1-9