A. Oni 9:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si rán ẹmi buburu sãrin Abimeleki ati awọn ọkunrin Ṣekemu; awọn ọkunrin Ṣekemu si fi arekereke bá Abimeleki lò:

A. Oni 9

A. Oni 9:13-24