A. Oni 18:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Dani si ba ọ̀na wọn lọ: nigbati Mika si ri i pe, nwọn lagbara jù on lọ, on si yipada, o si pada lọ sinu ile rẹ̀.

A. Oni 18

A. Oni 18:22-31