A. Oni 17:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rọ̀ ọmọ Lefi na lọrùn lati bá ọkunrin na joko; ọmọkunrin na si wà lọdọ rẹ̀ bi ọkan ninu awọn ọmọ rẹ̀.

A. Oni 17

A. Oni 17:7-13