A. Oni 12:8-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

8. Lẹhin rẹ̀ ni Ibsani ara Beti-lehemu ṣe idajọ Israeli.

9. O si lí ọgbọ̀n ọmọkunrin, ati ọgbọ̀n ọmọbinrin ti on rán lọ si ode, o si fẹ́ ọgbọ̀n ọmọbinrin lati ode wá fi fun awọn ọmọkunrin rẹ̀. On si ṣe idajọ Israeli li ọdún meje.

10. Ibsani si kú, a si sin i ni Beti-lehemu.

A. Oni 12