A. Oni 1:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Efraimu kò si lé awọn ara Kenaani ti ngbé Geseri jade; ṣugbọn awọn ara Kenaani ngbé ãrin wọn ni Geseri.

A. Oni 1

A. Oni 1:20-36