Timoti Kinni 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

òun nìkan tí kì í kú, tí ó ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí eniyan kò lè súnmọ́, tí ẹnikẹ́ni kò rí rí, tí eniyan kò tilẹ̀ lè rí. Tirẹ̀ ni ọlá ati agbára tí kò lópin. Amin.

Timoti Kinni 6

Timoti Kinni 6:11-21