Timoti Kinni 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sọ fún ọ, níwájú Ọlọrun ati Kristi Jesu, ati àwọn angẹli tí Kristi ti yàn, pé kí o pa ọ̀rọ̀ yìí mọ́; má ṣe ojuṣaaju.

Timoti Kinni 5

Timoti Kinni 5:12-25