Sefanaya 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ti mú ẹ̀bi yín kúrò,ó sì ti lé àwọn ọ̀tá yín lọ.OLUWA, ọba Israẹli wà lọ́dọ̀ yín;ẹ kò sì ní bẹ̀rù ibi mọ́.

Sefanaya 3

Sefanaya 3:9-17