Sefanaya 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi OLUWA yóo dojú ìjà kọ ìhà àríwá, n óo pa ilẹ̀ Asiria run; n óo sọ ìlú Ninefe di ahoro, ilẹ̀ ibẹ̀ yóo sì gbẹ bí aṣálẹ̀.

Sefanaya 2

Sefanaya 2:6-15