Samuẹli Kinni 30:27-29 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Ó fi ranṣẹ sí àwọn tí wọ́n wà ní Bẹtẹli, ati àwọn tí wọ́n wà ní Ramoti ti Nẹgẹbu, ati Jatiri;

28. ati àwọn tí wọ́n wà ní Aroeri, Sifimoti, ati ní Eṣitemoa;

29. ní Rakali, ní àwọn ìlú Jerameeli, àwọn ìlú Keni,

Samuẹli Kinni 30