Samuẹli Kinni 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, n óo ṣe gbogbo ohun tí mo ti sọ pé n óo ṣe sí ìdílé Eli, láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:11-21