Samuẹli Kinni 28:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dáhùn pé, “Ó dára, o óo sì rí ohun tí èmi iranṣẹ rẹ lè ṣe.”Akiṣi bá ní, òun óo fi Dafidi ṣe olùṣọ́ òun títí lae.

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:1-8