Samuẹli Kinni 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, sọ ohun tí o rí fún mi.”Obinrin náà dáhùn pé, “Mo rí ẹbọra kan, tí ń jáde bọ̀ láti inú ilẹ̀.”

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:6-22