Samuẹli Kinni 24:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lónìí, o ti fi bí o ti jẹ́ eniyan rere sí mi tó hàn mí, nítorí pé o kò pa mí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLUWA fi mí lé ọ lọ́wọ́.

Samuẹli Kinni 24

Samuẹli Kinni 24:13-22