Samuẹli Kinni 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sá kúrò ní Naioti, ní Rama, lọ sọ́dọ̀ Jonatani, ó sì bi í pé, “Kí ni mo ṣe? Ìwà burúkú wo ni mo hù? Ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo ṣẹ baba rẹ tí ó fi ń wọ́nà láti pa mí?”

Samuẹli Kinni 20

Samuẹli Kinni 20:1-7