Samuẹli Kinni 18:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn gbogbo àwọn ará Israẹli ati Juda ni wọ́n fẹ́ràn Dafidi, nítorí ó jẹ́ olórí tí ń ṣe àṣeyọrí.

Samuẹli Kinni 18

Samuẹli Kinni 18:8-18