Samuẹli Kinni 17:37 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tí ó gbà mí lọ́wọ́ kinniun ati beari yóo gbà mí lọ́wọ́ Filistini yìí.”Saulu bá sọ fún Dafidi pé, “Máa lọ, OLUWA yóo wà pẹlu rẹ.”

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:27-42