Samuẹli Kinni 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Filistini kó ara wọn jọ sí Soko, ìlú kan ní ilẹ̀ Juda láti bá Israẹli jagun. Wọ́n pa ibùdó wọn sí Efesi Damimu, tí ó wà láàrin Soko ati Aseka.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:1-6