Samuẹli Kinni 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà dáhùn pé, “Rárá o, o kò rẹ́ wa jẹ rí, o kò ni wá lára, bẹ́ẹ̀ ni o kò sì gba ohunkohun lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni rí.”

Samuẹli Kinni 12

Samuẹli Kinni 12:1-14