Samuẹli Kinni 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, lẹ́yìn tí wọ́n jẹ, tí wọ́n mu tán, ninu ilé OLUWA, ní Ṣilo, Hana dìde. Eli, alufaa wà ní ìjókòó lórí àpótí, lẹ́bàá òpó ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:4-15