Samuẹli Keji 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Mẹfiboṣẹti, ẹni tí ẹsẹ̀ rẹ̀ mejeeji ti rọ ṣe bẹ̀rẹ̀ sí gbé Jerusalẹmu, ó sì ń jẹun lọ́dọ̀ ọba nígbà gbogbo.

Samuẹli Keji 9

Samuẹli Keji 9:10-13