Samuẹli Keji 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun gbígbóná bẹ́ sílẹ̀ ní ọjọ́ náà, ṣugbọn àwọn eniyan Dafidi ṣẹgun Abineri ati àwọn eniyan Israẹli.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:12-20