Samuẹli Keji 18:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé òkú Absalomu jù sinu ihò jíjìn kan ninu igbó, wọ́n sì kó ọpọlọpọ òkúta jọ sórí òkú rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọ ogun Israẹli bá sá, olukuluku gba ilé rẹ̀ lọ.

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:9-18