Samuẹli Keji 15:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Oníṣẹ́ kan wá ròyìn fún Dafidi pé, “Ọkàn gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ti ṣí sí ọ̀dọ̀ Absalomu.”

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:9-16