Sakaraya 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lára àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ti oko ẹrú Babiloni dé, mú Helidai, Tobija ati Jedaaya lẹsẹkẹsẹ, kí o lọ sí ilé Josaya ọmọ Sefanaya.

Sakaraya 6

Sakaraya 6:1-12