Sakaraya 10:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Wọn óo la òkun Ijipti kọjá,ìgbì rẹ̀ yóo sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.Odò Naili yóo gbẹ kanlẹ̀,a óo rẹ ìgbéraga ilẹ̀ Asiria sílẹ̀,agbára óo sì kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti.

12. N óo sọ wọ́n di alágbára ninu èmi OLUWA,wọn yóo sì máa ṣògo ninu orúkọ mi.”

Sakaraya 10