Rutu 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn obinrin bá sọ fún Naomi pé, “Ìyìn ni fún OLUWA, tí kò ṣe ọ́ ní aláìní ìbátan, kí OLUWA ṣe ọmọ náà ní olókìkí ní Israẹli.

Rutu 4

Rutu 4:4-19