Romu 3:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ó wà ní àkọsílẹ̀ bẹ́ẹ̀ pé,“Kò sí ẹnìkan tí ó jẹ́ olódodo; kò sí ẹnìkankan.

11. Kò sí ẹni tí òye yé,kò sí ẹni tí ó ń wá Ọlọrun.

12. Gbogbo wọn ti yapa kúrò lójú ọ̀nà,gbogbo wọn kò níláárí mọ́,kò sí ẹni tí ó ń ṣe rere,kò sí ẹnìkan.

Romu 3