Peteru Kinni 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kí àwọn tí ó ń jìyà nípa ìfẹ́ Ọlọrun fi ọkàn wọn fún Ọlọrun nípa ṣíṣe rere. Ọlọrun Ẹlẹ́dàá kò ní dójú tì wọ́n.

Peteru Kinni 4

Peteru Kinni 4:9-19